2 Kíróníkà 20:27 BMY

27 Nígbà náà wọ́n darí pẹ̀lú Jéhóṣáfátì, gbogbo àwọn ènìyan Júdà àti Jérúsálẹ́mù padà pẹ̀lú ayọ̀ sí Jérúsálẹ́mù, nítorí Olúwa ti fún wọn ní ìdí láti yọ̀ lórí àwọn ọ̀tá wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:27 ni o tọ