28 Wọ́n sì wọ Jérúsálẹ́mù, wọ́n sì lọ sí ilé Olúwa pẹ̀lú ohun èlò orin àti dùùrù àti ipè.
Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20
Wo 2 Kíróníkà 20:28 ni o tọ