2 Kíróníkà 20:29 BMY

29 Ìbẹ̀rù Ọlọ́run wá si orí gbogbo ìjọba ilẹ̀ náà nígbà tí wọ́n gbọ́ bí Olúwa ti bá àwọn ọ̀ta Ísírẹ́lì jà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:29 ni o tọ