2 Kíróníkà 21:19 BMY

19 Ní àkókò kan ní ìparí ọdún kejì, àwọn ìfun rẹ̀ jáde nítorí àrùn náà ó sì kú nínu ìrora ńlá. Àwọn Ènìyàn rẹ̀ kò dá iná láti fi bọlá fún un, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe fún àwọn baba a rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 21

Wo 2 Kíróníkà 21:19 ni o tọ