2 Kíróníkà 21:20 BMY

20 Jéhórámù jẹ́ ẹni ọdún méjìlélọ́gbọ̀n (32) ní ìgbà tí ó di ọba, Ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́jọ. Ó kọjá lọ, kò sí ẹni tí ó kábàámọ̀. A sì sin ín si ìlú ńlá ti Dáfídì. Ṣùgbọ́n kì í ṣe nínú ibojì àwọn ọba.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 21

Wo 2 Kíróníkà 21:20 ni o tọ