2 Kíróníkà 22:8 BMY

8 Nígbà tí Jéhù ń ṣe ìdájọ́ lórí ilé Áhábù. Ó rí ọmọbìrin ọba ti Júdà àti àwọn ọmọkùnrin ìbátan Áhásì. Tí ó ń dásí Áhásáyà, ó sì pa wọ́n.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 22

Wo 2 Kíróníkà 22:8 ni o tọ