2 Kíróníkà 24:26 BMY

26 Àwọn tí ó dìtẹ̀ sì jẹ́ Ṣábádì, ọmọ Ṣíméátì arábìnrin Ámónì àti Jóhéṣábádì ọmọ Ṣímírítì arábìnrin Móábì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 24

Wo 2 Kíróníkà 24:26 ni o tọ