2 Kíróníkà 24:27 BMY

27 Àkọsílẹ̀ àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn ọ̀pọ̀ lọ́pọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ nípa rẹ̀, àti àkọsílẹ̀ ti ìmúpadà sípò ilé Ọlọ́run ní a kọ sínú ìwe ìtumọ̀ ti àwọn ọba. Ámásáyà ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 24

Wo 2 Kíróníkà 24:27 ni o tọ