2 Kíróníkà 24:9 BMY

9 A ṣe ìkéde ní Júdà àti Jérúsálẹ́mù wí pé wọ́n gbọdọ̀ mú wá fún Olúwa, owó orí tí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa ti bèèrè lọ́wọ́ Ísírẹ́lì ní ihà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 24

Wo 2 Kíróníkà 24:9 ni o tọ