2 Kíróníkà 29:36 BMY

36 Heṣekáyà sì yọ̀, àti gbogbo ènìyàn pé, Ọlọ́run ti múra àwọn ènìyàn náà sílẹ̀, nítorí lójijì ni a ṣe nǹkan náà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:36 ni o tọ