2 Kíróníkà 3:13 BMY

13 Ìyẹ́ apá àwọn kérúbù wọ̀nyìí gbà tó ogún ìgbọ̀nwọ́. Wọ́n dúró ní ẹsẹ̀ wọn, wọ́n kọjú sí yàrá pàtàkì ńlá naà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:13 ni o tọ