2 Kíróníkà 3:14 BMY

14 Ó ṣe aṣọ títa ní àwọ̀ ojú ọ̀run, àwọ̀ àlùkò àti àwọ̀ pupa fòò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ pẹ̀lú kérúbù tí a se sórí i rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:14 ni o tọ