2 Kíróníkà 3:15 BMY

15 Níwájú ilé Olúwa náà ó ṣe òpó méjì tí lápapọ̀ jẹ́ márùn ún dín lógójì ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, olúkúlùkù pẹ̀lú olórí lórí rẹ̀ tí o ń wọn ìgbọ̀nwọ́ márùn ún.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:15 ni o tọ