2 Kíróníkà 31:3 BMY

3 Ọba dá láti ara ohun ìni rẹ̀ fun ọrẹ sísun àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́ àti fún ọrẹ sísun ní ọjọ́ ìsinmi, òṣùpá tuntun àti àsè yíyàn gẹ́gẹ́ bi a ti se kọ ọ́ nínú òfin Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:3 ni o tọ