2 Kíróníkà 31:4 BMY

4 Ó pàsẹ fún àwọn ènìyàn tí ń gbé ní Jerúsálẹ́mù láti fi ìpín tí ó yẹ fún àlùfáà fún un àti àwọn ará Léfì, kí wọn kí ó lè fi ara wọn jìn fún òfin Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:4 ni o tọ