2 Kíróníkà 35:10 BMY

10 Nítorí náà, a múra ìsìn náà sílẹ̀, àwọn àlùfáà sì dúró ní ipò wọn pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì nípa iṣẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ọba ti pa á lásẹ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:10 ni o tọ