2 Kíróníkà 35:11 BMY

11 Ní ti àjọ ìrékọjá a sì pa ẹran, àwọn àlùfáà sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà tí wọ́n gbé sí ọwọ́ wọn, nígbà tí àwọn ọmọ Léfì sì bo ẹranko.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:11 ni o tọ