2 Kíróníkà 36:14 BMY

14 Síwájú síi gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn ènìyàn sì di ẹni tí ń dẹ́ṣẹ̀ gidigidi, pẹ̀lú gbogbo ìríra àwọn orílẹ̀ èdè wọ́n sì sọ ilé Olúwa di èérí, tí ó ti yà sí mímọ́ ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:14 ni o tọ