2 Kíróníkà 36:15 BMY

15 Olúwa, Ọlọ́run àwọn baba wọn ránsẹ́ sí wọn láti ọwọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣíwájú àti ṣíwájú síi, nítorí tí ó ní ìyọ́nú sí àwọn ènìyàn rẹ̀ àti sí ibùgbé rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:15 ni o tọ