2 Kíróníkà 36:2 BMY

2 Jehóáhásì sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́talélọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ni Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́ta.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:2 ni o tọ