2 Kíróníkà 36:20 BMY

20 Ó sì kó èyí tí ó kù lọ sí Bábílónì àwọn tí ó rí ibi sá láti ẹnu idà wọ́n sì di ìránṣẹ́ fún un àti àwọn ọmọ rẹ̀ títí tí ìjọba Pásíà fi gba agbára.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:20 ni o tọ