2 Kíróníkà 36:21 BMY

21 Ìlẹ̀ náà sì gbádùn ìsinmi rẹ̀, ní gbogbo ìgbà ìdahoro, òun sì ń sinmi títí ó fi di àádọ́rin ọdún (70) fi pé ní ìmúsẹ ọ̀rọ̀ Olúwa tí a sọ láti ẹnu Jeremíà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:21 ni o tọ