2 Kíróníkà 36:4 BMY

4 Ọba Éjíbítì sì mú Élíákímù, arákùnrin Jehóáhásì, jẹ ọba lórí Júdà àti Jérúsálẹ́mù, ó sì yí orúkọ Eliákímù padà sí Jéhóíákíámù, ṣùgbọ́n Nékò mú arákùnrin Eliákímù, Jehóáhásì ó sì gbé e lórí Éjíbítì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:4 ni o tọ