2 Kíróníkà 36:5 BMY

5 Jéhóíákímù sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún méjìlá. Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa Ọlọ́run rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:5 ni o tọ