2 Kíróníkà 36:8 BMY

8 Ìyòókù isẹ́ ìjọba Jéhóíákíámù, àwọn ohun ìríra tí ó ṣe àti gbogbo ohun tí a rí nípa rẹ̀, ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba Ísírẹ́lì àti Júdà. Jéhóíákínì ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:8 ni o tọ