2 Kíróníkà 36:7 BMY

7 Nebukadínésárì pẹ̀lú mú-un lọ sí Bábílónì, ohun èlò láti ilé Olúwa, ó sì mú wọn lọ sí ààfin tirẹ̀ níbẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:7 ni o tọ