2 Kíróníkà 5:10 BMY

10 Kò sí ohun kan nínú àpótí ẹ̀rí náà bí kò ṣe síléètì méjì tí Mósè fi sínú rẹ̀ ní Hórébù, ní ìgbà tí Olúwa fi bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n jáde wá láti ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:10 ni o tọ