2 Kíróníkà 5:11 BMY

11 Lẹ́yìn náà ni àwọn àlùfáà jáde wá láti ibi mímọ́. Gbogbo àwọn àlùfáà tí ó wà níbẹ̀ ni ó ya ara wọn sí mímọ́ láìbìkítà fún ìpín wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:11 ni o tọ