2 Kíróníkà 6:19 BMY

19 Síbẹ̀ ṣe àfiyèsí àdúrà ìránṣẹ́ rẹ àti ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ fún àánú, Olúwa Ọlọ́run mi, gbọ́ ẹkún àti àdúrà tí ìránṣẹ́ rẹ̀ ń gbà níwájú rẹ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:19 ni o tọ