2 Kíróníkà 6:20 BMY

20 Kí ojú rẹ kí ó lè sí sí ilé Olúwa ní ọ̀sán àti lóru, ní ibí yìí tí ìwọ ti wí pé ìwọ yóò fi orúkọ rẹ síbẹ̀. Kí ìwọ kí ó gbọ́ àdúrà tí ìránṣẹ́ rẹ ń gbà lórí ibí yìí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:20 ni o tọ