2 Kíróníkà 7:1 BMY

1 Nígbà tí Sólómónì sì ti parí àdúrà, iná sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run ó sì jó ọrẹ sísun àti ẹbọ, ògo Ọlọ́run sì kún ilé Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 7

Wo 2 Kíróníkà 7:1 ni o tọ