2 Kíróníkà 7:7 BMY

7 Sólómónì sì yà sọ́tọ̀ láàrin àgbàlá níwájú ilé Olúwa, níbẹ̀ sì ni ó ti se ìrúbọ ọrẹ sísun àti ọ̀rá ẹbọ àlàáfíà, nítorí pẹpẹ idẹ tí ó ti ṣe kò lè gba ọrẹ sísun, àti ọrẹ oúnjẹ, àti ọ̀rá náà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 7

Wo 2 Kíróníkà 7:7 ni o tọ