2 Kíróníkà 7:8 BMY

8 Bẹ́ẹ̀ ni Sólómónì se àsè ní àkókò náà fún ọjọ́ méje àti gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pẹ̀lú rẹ̀ àti ìjọ ènìyàn ńlá, àwọn ènìyàn láti Lébò Hámátì títí dé odò Éjíbítì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 7

Wo 2 Kíróníkà 7:8 ni o tọ