2 Kíróníkà 9:21 BMY

21 Ọba ní ọkọ̀ tí a fi ń tajà tí àwọn ọkùnrin Húrámù ń bojútó. Ẹ̀kan ní ọdún mẹ́ta ni ó máa ń padà, ó ń gbé wúrà àti fàdákà àti eyín erin, àti ìnàkí àti ẹyẹ ológe wá.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:21 ni o tọ