2 Kíróníkà 9:22 BMY

22 Ọba Solómónì sì tóbi nínú ọlá ńlá àti ọgbọ́n ju gbogbo àwọn ọba tí ó kù lórí ilẹ̀ ayé lọ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:22 ni o tọ