2 Kíróníkà 9:23 BMY

23 Gbogbo àwọn ọba ayé ń wá ojú rere lọ́dọ̀ Sólómónì láti gbọ́n ọgbọ́n tí Ọlọ́run ti fi sínú ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:23 ni o tọ