2 Sámúẹ́lì 11:27 BMY

27 Nígbà tí ìṣọ̀fọ̀ náà sì kọjá tan, Dáfídì sì ránṣẹ́, o sì mú un wá sí ilé rẹ̀, ó sì di aya rẹ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan fún un, ṣùgbọ́n nǹkan náà tí Dáfídì ṣe burú níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 11

Wo 2 Sámúẹ́lì 11:27 ni o tọ