2 Sámúẹ́lì 12:24 BMY

24 Dáfídì sì ṣìpẹ̀ fún Bátíṣébà aya rẹ̀, ó sì wọlé tọ̀ ọ́, ó sì bá a dàpọ̀: òun sì bí ọmọkùnrin kan, Dáfídì sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Sólómónì: Olúwa sì fẹ́ ẹ.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 12

Wo 2 Sámúẹ́lì 12:24 ni o tọ