2 Sámúẹ́lì 13:1 BMY

1 Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Ábúsálómù ọmọ Dáfídì ní àbúrò obìnrin kan tí ó ṣe arẹwà, orúkọ rẹ̀ a sì máa jẹ́ Támárì; Ámúnónì ọmọ Dáfídì sì fẹ́ràn rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 13

Wo 2 Sámúẹ́lì 13:1 ni o tọ