2 Sámúẹ́lì 13:22 BMY

22 Ábúsálómù kò sì bá Ámíúnónì sọ nǹkan rere, tàbí búburú: nítorí pé Ábúsálómù kóríra Ámúnónì nítorí èyí tí ó ṣe, àní tí ó fi agbára mú Támárì àbúrò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 13

Wo 2 Sámúẹ́lì 13:22 ni o tọ