29 Àwọn ìránṣẹ́ Ábúsálómù sì ṣe sí Ámúnónì gẹ́gẹ́ bí Ábúsálómù ti páṣẹ. Gbogbo àwọn ọmọ ọba sì dìde, olúkúlukú gun ìbaka rẹ̀, wọ́n sì sá.
Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 13
Wo 2 Sámúẹ́lì 13:29 ni o tọ