2 Sámúẹ́lì 13:33 BMY

33 Ǹjẹ́ kí Olúwa mi ọba má ṣe fi nǹkan yìí sí ọkàn pé gbogbo àwọn ọmọ ọba ni o kú: nítorí Ámúnónì nìkan ṣoṣo ni ó kú.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 13

Wo 2 Sámúẹ́lì 13:33 ni o tọ