2 Sámúẹ́lì 13:36 BMY

36 Nígbà tí ó sì parí ọ̀rọ̀ tí ó ń sọ, sì wò ó àwọn ọmọ ọba dé, wọ́n sì gbé ohùn wọn sòkè, wọ́n sì sunkún: ọba àti gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú sì sọkún ńláńlá.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 13

Wo 2 Sámúẹ́lì 13:36 ni o tọ