2 Sámúẹ́lì 14:27 BMY

27 A sì bí ọmọkùnrin mẹ́ta fún Ábúsálómù àti ọmọbìnrin kan ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Támárì: òun sì jẹ́ obìnrin tí ó lẹ́wà lójú.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 14

Wo 2 Sámúẹ́lì 14:27 ni o tọ