2 Sámúẹ́lì 14:31 BMY

31 Jóábù sì dìde, ó sì tọ Ábúsálómù wá ní ilé, ó sì wí fún un pé, “Èéṣe tí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ fi tinábọ oko mi?”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 14

Wo 2 Sámúẹ́lì 14:31 ni o tọ