2 Sámúẹ́lì 15:16 BMY

16 Ọba sì jáde, gbogbo ilé rẹ̀ sì tẹ̀lé e. Ọba sì fì mẹ́wàá nínú àwọn obìnrin rẹ̀ sílẹ̀ láti máa sọ́ ilé.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15

Wo 2 Sámúẹ́lì 15:16 ni o tọ