19 Ọba sì wí fún Ítaì, ará Gítì pé, “Èéṣe tí ìwọ fi ń bá wa lọ pẹ̀lú, padà, kí o sì ba ọba jókòó; nítorí pé aléjò ni ìwọ, ìwọ sì ti fi ìlú rẹ sílẹ̀.
Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15
Wo 2 Sámúẹ́lì 15:19 ni o tọ