21 Ítaì sì dá ọba lóhùn, ó sì wí pé, “Bí Olúwa tí ń bẹ láàyè, àti bí Olúwa mi ọba ti ń bẹ láàyè, nítòótọ́ níbikíbi tí Olúwa mi ọba bá gbé wà, ìbáà ṣe nínú ikú, tàbí nínú ìyè, níbẹ̀ pẹ̀lú ni ìránṣẹ́ rẹ yóò gbé wà.”
Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15
Wo 2 Sámúẹ́lì 15:21 ni o tọ