2 Sámúẹ́lì 16:13 BMY

13 Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì ń lọ ní ọ̀nà, Ṣíméhì sì ń rìn lẹ́bá òkè tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ó sì ń yan èébú bí ó ti ń lọ, ó sì ń sọ ọ́ lókúta, ó sì ń fọ́n erùpẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 16

Wo 2 Sámúẹ́lì 16:13 ni o tọ