2 Sámúẹ́lì 16:8 BMY

8 Olúwa mú gbogbo ẹ̀jẹ̀ ìdílé Ṣọ́ọ̀lù padà wá sí orí rẹ, ní ipò ẹni tí ìwọ jọba; Olúwa ti fi ijọba náà lé Ábúsálómù ọmọ rẹ lọ́wọ́: sì wò ó, ìwà búburú rẹ ni ó mú èyí wá bá ọ, nítorí pé ọkùnrin ẹ̀jẹ̀ ni ìwọ.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 16

Wo 2 Sámúẹ́lì 16:8 ni o tọ